Ọlọ́run, Níbo Lo Wá?

Available
0
StarStarStarStarStar
0Reviews

A bí Adéọlá Ọrẹolúwa Adéfẹ̀sọ̀ ní ìpínlẹ̀ Ògùn ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ṣe èwe rẹ̀ nínú ayọ̀ àti ìdùnnú. Àwọn òbí rẹ̀ àgbà ní ìdílé ìyá ló tọ́ ọ dàgbà pẹ̀lú ìfẹ́ tó wàyàmì àti ẹ̀kọ́ ìwé tó yè kooro, òun náà sì dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ akọrin agbègbè ibẹ̀. Ṣùgbọ́n nǹkan yí bìrí nígbà tí ó kó sí wàhálà abẹ́ ilé látàrí ìjìyà tí ó ń rí láti ọ̀dọ̀ ọkọ rẹ̀. Inú làásìgbò ìjìyà ara àti ọkàn yìí ló wà tí ó fi p...

Read more
product_type_E-book
epub
Price
9.99 £

Follow the Author

Options

  • Formats: epub
  • ISBN: 9781636031217
  • Publication Date: 22 Nov 2021
  • Publisher: Distributed By Ingram Spark
  • Product language: Yoruba
  • Drm Setting: DRM